Smiley face

"Asewo ni awon omo ile igbimo asofin Naija wa lo silu Amerika" Asoju ile Amerika siluu Naijiria lo so bee

https://m.facebook.com/photo.php?fbid=281003148918346&id=100010259880311&set=gm.1213120382072602&refid=18&_ft_=qid.6297500802755197719%3Amf_story_key.1213120382072602%3Atl_objid.1213120382072602&__tn__=E
Awon omo ile igbimo asoju-sofin Abuja meta ni asoju ile Amerika sile Naijiria ti fesun kan bayii latari bi okan ninu se bu ikebe omobirin osise ile itura ti won desi nigba ti won rin irin ajo lo siluu Amerika.

Nigba ti awon meji yoku be onimoto to wa won lowe lati ba won wa awon omoge asewo ti idi won dabi katapila ti won le ba sun mojumo.

Bee ise ilu ni won ran awon meteeta lati soju ile igbimo asofin Naijiria nibi ipade kan pataki niluu Amerika.

Awon asoju-sofin naa ni Samuel Ikon (PDP, Akwa Ibom), Mohammed Gololo (APC, Bauchi) ati Mark Gbillah (APC, Benue).

Ti won ba jebi esun yii looto, iru ijiya wo le lero wi pe o to si won?

E ka ero awon eniyan NIBI
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment