Smiley face

Ero awon eniyan nipa rugudu oro esin ti n lo nipinle Osun

https://m.facebook.com/groups/250287078355942?view=permalink&id=1211818635536110&refid=18&_ft_=qid.6297500802973412513%3Amf_story_key.1211818635536110%3Atl_objid.1211818635536110
Bi o tile je wi pe Gomina ipinle osun, Ogbeni Rauf Aregbesola ti pase wi pe, omoleewe kankan ti won ba tun ri ninu aso adura ninu ileewe yoo je iyan re nisu.

Sugbon sa, awada ni awon kan an fi baba Kabiru se nigba ti won so wi pe, awon omo idile eleegun, oloya, onisango ko ni pe gbe "swagger" ti won naa yo.

Awon kan ni oro naa le jo bi awada, sugbon o seese ko je wi pe ibi toro yoo kangun si nu-un nipinle Osun pelu bi nnkan ti n lo bayii.

Eyin ojogbon, e ba wa dasi NIBI


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment