Smiley face

Aso oge ti ko gba ijokoo gbayi loju

https://m.facebook.com/photo.php?fbid=281007915584536&id=100010259880311&set=gm.1213129442071696&refid=18&_ft_=qid.6297507623239241415%3Amf_story_key.1213129442071696%3Atl_objid.1213129442071696&__tn__=E
Aso oge tuntun ti awon sabere-dowo ilu okeere tun gbe jade ni yii. Won ni ti eniyan ba wo aso naa de agbo ariya, ko saaye fun ijokoo rara, nitori ike niwon somo owo isale aso naa.

Nje a le so wi pe iru aso oge bayii mogbon dani? Idahun wa NIBI


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment