Smiley face

Dbanj omo olojo-ibi ti gbegba ope

Oladapo Daniel Oyebanjo ti gbogbo eniyan mo si Dbanj, ogbontarigi onkorin ile Naijiria, le lodun lonii ojo kesan-an osu kefa odun.


Nibayii Kokomaster ti bere si ni fi emi imoore han si Olorun, awon obi re ati gbogbo awon ololufe re pata fun ipa ti won ko lati mu ala re se.

Ilu Kaduna ni won bi Bangalee si, nigba to di odun 2004 lo bere si ni korin sise se lojulowo.

Lara awon orin re ni "Fall In Love" to se lodun 2008, Oliver Twist -2012, Knocking On My Door - 2015.

Adura a wa ni wi pe Eja Nla yoo ma dagba sii ninu ola, ayo, okiki ati emi gigun.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment