Smiley face

Igbiyanju eda nile aye: Omo ileewe ti n ta iresi ko le jeeyan laye

Ipokipo ti eda ba ti ba ara re ko ma dupe, kosi ma dekun lati tesiwaju ninu ilakaka ati igbiyanju re lati moke.

Gege bi oro Seun Awodele, The Anointed Presenter, "Eda to ba fe tan laye, o ni lati ni itan".

O ni le koro, sugbon o daju wi pe ola yoo dun joyin lo.



Orisun foto: Olalekan Israel Odutan/Facebook

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment