Smiley face

Se aso oge leyii abi akisa?

Sebi wẹrewẹrẹ nikan n jẹle, to ba ya, awon omoge iwoyii ko ni wo nnkankam sidi mọ rara to jẹ wi pe ihoho lasan ni gbogbo won yoo ma rin. A bi ewo tun leyii?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment