Smiley face

Kini Obasanjo lo ba Buhari so lonii ni Aso Rock?


Won tun ti kofiri Olusegun Aremu Obasanjo nile ijoba apapọ to wa niluu Abuja lonii (June 3). Obasanjo se ipade pọ pẹlu Aare Buhari ni kọkọ lawọn meji nikan.
Sugbon awon onwoye lagbo oselu ni, oseese ki Obasanjọ lo tọ Buhari sọna lori awon ọrọ kan to se koko nipa ato Naijiria.

Awon kan tilẹ ni, o seese ko jẹ oro awon ọmọ agbegbon Niger Delta tuntun ti won sese dide ti won pe ara won ni Niger Delta Avenger lo mu Aremu yọju si Aso Rock.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment