Smiley face

Ayọ ọmọ tuntun: Wèrè bimọ soju titi

Obirin wèrè oloyun kan lo sadeede n rọbi loju pọpọna ki awon abiyamọ aye to sun mọ ọ lati se iranlowo fun un. Obirin lọmọ to bi, orileede Zambia ni islẹ naa ti waye. Ọkunrin kan ti orukọ rẹ n jẹ Victor lo si gbe aworan naa sori Facebook.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment