Smiley face

"Leyin iku iyawo kẹta, Jide Kosoko le ma fi won soogun": Omo gomina lo sọ bẹẹ

Jide Kosoko
Kemi Omololu-Olunloy, omo gomina ipinle Oyo nigba kan ri, ti fsun kan Jide Kosoko wi pe, oseese ko je wi pe o n fi awon iyawo rẹ soogun ni. Henrietta Kosoko ni yoo je iyawo ẹlẹẹkẹta ti yoo ku nile Jide Kosoko.

Ninu alaye Kemi, o ni pupọ awon onitiata ni won maa soogun lati wa agbara.

Nibayii, Kemi ti n pe wi pe, ki won tana wadii Jide Kosoko, ko ma lo je wi pe oun ni i lo awon aya rẹ lati fi bori.
Kemi Omololu-Olunloyo
 
" NOLLYWOOD AND RITUALISM
Actor Jide Kosoko's third wife just died. The light skin bleaching ‪#‎Nollywood‬ actor. This makes it three wives dead. He is now technically a black widower. He should be investigated for ritualism and the occult world. Something I hear is very prevalent in Nollywood."
Henrietta Kosoko
E ma gbagbe wi pe, Kemi kan naa yii ti fi igba kan pe baba rẹ loloogun, iyen Victor Omololu-Olunloyo, gomina ipinle Oyo to je laarin October 1983 si December 1983.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment