Smiley face

"Ori Kòsẹlèrí l'Ọyọ ti daru"- Asiwaju Adekola Adeoye

Pelu Ohun ti n sẹlẹ lọwọlọwọ bayii nipinlẹ Ọyọ, awon eniyan ti n fi ero won han NIBI nipa isejoba Gomina Abiola Ajimobi ti ipinle Oyo.

Okan ninu awon asaaju ọdọ ẹgbẹ Accord nipinle Oyo, Asiwaju Adekola Adeoye, lo tun gbe eleyii jade:

"Lá tayé Bólá-Ìgè, Òyo ò bajé, tófi dórí ADÉWÒLÚ Òyó sì n dùn, Ó dorí # Kòselèrí , Òyó n dàrú,.."
Njẹ otito ni ọrọ Asiwaju Adekola Adeoye?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment