Smiley face

Saheed Osupa: Mr. Biggy

Ninu ero mi, mo ro wi pe o dara ju ki Saheed Osupa ma wọ iru awon asọ bayii lọpọ igba ju awon asọ ibilẹ lọ. 


Iru awon asọ bayii ma n rẹwa lara rẹ ju awon agbada tabi buba lọ. 

Ki wa ki i se wi pe awon agbada ati buba naa burẹwa lorun rẹ, o kan jẹ wi pe, iru awon asọ bẹẹ ma n je ki Oba orin dabi agbalagba.

Kini ero ti yin?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment