Smiley face

Iroyin agbọsọgbanu: Stephen Keshi ti ku o

Stephen Keshi
A ti gbọ iku akọnimọọgba ẹgbẹ agbabọọlu Naijiria nigba kan ri, Stephen Keshi. Ilu Benin ni okunrin naa ku si laarọ oni (08-06-16). Se ẹ ko gbagbe wi pe, laipe yii naa ni okunrin naa padanu aya rẹ.

Ekunrere iroyin n bọ laipe.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment