Smiley face

Samuel Eto'o so yigi alarinrin pelu iya awon omo re niluu Italy

Agbaboolu omo ile Cameroon, Samuel Eto'o, ti pada so yigi pelu ololufe re to tun je iya awon omo re meji, Georgette Tra, ninu Italo.

Igbeyawo alayo yii lo waye ni Stezzano to wa lorileede Italy.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment