Smiley face

Awon omo ileewe sagbako iku ojiji leyin ti won jo makosa tan

Awon omo ileewe giga kan niluu Kenya ni won ti sagbako iku ojiji lana, 1/7/06, nigba ti won ti ode ariya alaso funfun bo. Awon mejo ni iroyin so fun wa pe won ku ninu ijamba oko naa.





Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment