Smiley face

Baba Kemi Olunloyo tun ti soro leyin leta to jade laaro oni

Ti e ba n fi okan ba awon iroyin ti n jade lataaro bo. Ni aaro yii (08/07016) ni atejade kan jade eleyii ti a gbo wi pe o ti owo Victor Omololu Olunloyo, gomina ipinle Oyo tele, jade nipa omo re, Kemi Olunloyo.

Ninu atejade naa ni baba re ti so wi pe, omo naa ni arun opolo, eleyii ti a le so wi pe o fa sababi awon pupo ninu oro alufansa ti omo naa n lo lori ero ayelujara .

Atejade mii tun ti jade bayii, nibi ti baba naa ti so wi pe, oun ko ni oun gbe atejade to jade laaro yii jade.

Sugbon sa,awon kan ni oseese ko je baba naa lo gbe leta akoko naa jade. Sugbon ko da bi ogbon leyin to da oro naa ro, eleyii to ro wi pe o le se akoba tabi mu abuku de ba ebi oun.

Won ni o le je idi pataki ni yii ti baba naa fi ni leta naa ki i se lati owo oun.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment