Smiley face

Bayii ni awon omo ologun Naijiria se kirun yidi ti won loju ija.

Pelu ihamora ohun ija ogun ni awon omo ologun Naijiria ti won gbogun ti Boko Haram loke oya se kirun odun itunnu awe ti won.

Adupe wi pe ayo ni gbogbo re jasi leyin ijosin won si oba Allah. Ki Olorun tun maa se ade abo lori won.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment