Smiley face

Buhari ti fi ojo kan kun isimi itunnu awe Eid-el-Fitr

Aare Muhammadu Buhari
Latari osu ti won ko ri eleyii to sokunfa idi ti awe ramadan alapọnle ko fi wa sopin lana, Aare Muhammadu Buhari ti fi ọjọ kan kun ọjọ isimi awon osise bayii. 

Isimi to ye ko wa sopin l'Ọjọru, wesde (06/07/2016) ni won ti sun di Ọjọbọ, tosde (07/07/2016) bayii.

Bakan naa, a fi asiko yii ki awon musulumi aye pata wi pe, odun ayo ni gbogbo wa yoo se o. Amin
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment