Smiley face

E ku Sande oni oo

Eyin tia, e si ku Sande oni. Opo re la se laye. Aye padding la wa yii. Mo gbo wi pe awon iyawo ile naa ti n "pad" awon owo obe ti awon oko won fun won nile. Eniwee, ko si probileemu.

E ku isimi oni ati imusile ise ola.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment