Smiley face

Manija bank FCMB ti fibon pa ara re tori gbese

Manija banki First City Monument Bank (FCMB) Plc, Mr. Olisa Nwakoby, ti fi bajinatu fo ara re lori lojo Eti to koja yii niluu Eko.

Ohun ti a gbo ni wi pe, arakunrin Olisa to je manija banki lo towo bowe ti won fi ya awon onibara kan lowo ti n lo bi N350M eleyii ti awon to yawo naa si ti poora.

Iwadii awon oniroyin si so wi pe, oseese ko je wi pe ona aito ni Ogbeni Olisa fi gbe owo naa jade fun awon onibara naa eleyii to pada di aibale okan fun un.

Bakan naa ni awon kan wi pe, oseese ko tun ni asemase kan to se pamo eleyii ti asiri re ko ti tu sita.

Niwaju Pasito ni Olisah ti duro lojo Jimoh to koja yii ni agbegbe Lekki to wa ni erekusu Eko,o jewo ese re niwaju Oluwa, leyin eyi lo so fun pasito wi pe kan ba oun jise fun iyawo oun wi pe ko ma se itoju awon omo o.

Leyin to se eyi tan, o fa bajinatu jade, o si fi fo ara re lori, ori naa si fo kaakiri ileele soosi. Ki Oluwa ba wa te maanu naa si afefe rere.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment