Smiley face

E wa wo ohun t'OLU se fun Femo Lancaster

Ti eda ba n reti ire kan lodo Oluwa, ti ire naa ko ba ti de, a dabi eni wi pe eni naa ko si ninu ajenda Olorun ni.

Sugbon akosile eda ko ni tase.

Femi Fadipe ti gbogbo eniyan mo si Femo Lancaster ni Oluwa tun ti fi omobirin tuntun alayo dalola bayii leyin akobi re okunrin.

Inu omokunrin olorin juju naa dun, ko si le pa ayo naa mora pelu bo se seranti odun mesan-an leyin igbeyawo re eleyii ti ko lomo ninu ko to wa bi akobi re.

Orisiirisii ni awon eniyan n so nigboro, sugbon nigba ti Olorun Lancaster setan, ona iyanu logbe aye re gba.

"After 9years plus of our marriage, God blessed us with a bouncing baby boy ''TOluwalase'' Today again, God added
another bouncing beautiful baby girl to my family.

''O ti mu mi gba gbe won ooo...ibanuje igba kan...A se were ni ise
Oluwa...'' .

Thank you Lord! Thank you Lord!! Thank you Lord!!!" - Femi Fadipe

Gbogbo wa la ba Otunba Femi Fadipe yo, fun Oba ti ko fi kan gba kan lowo re.

A si gbadura wi pe, ayo re ko ni dibanuje laelae. Amin
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment