Smiley face

Mike Bamiloye seranti Ogbon (30) odun lori itage

Mike Bamiloye, oludasile Mount Zion Faith Ministries, se iranti ogbon odun (30) to ti bere ise emi pelu aya re, Gloria Bamiloye.

"This day 30 years ago, I and Gloria was on stage presentation of "HELL IN CONFERENCE", the First Drama
production of Mount Zion Faith Ministries, Nigeria.

It was July 11th, 1986, it was 30 years ago." - Mike Bamiloye


Ko si tabi-sugbon, Edua oke ti fere si ise won. Bakan naa, aimoye ise iranse onitia lo ti ti ipase won dide ti awon naa si ti daduro.

Gege bi oro Mike Bamiloye, fiimu to n lo bi aadoje (130) ni ile ise iranse won ti gbe jade. Bakan naa ni won si ti ni telifisan sinima kristeni eleyii to je akoko iru e nile adulawo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment