Smiley face

Ipinle Oyo: Se ka fi ireti wa sinu Seyi Makinde?

Ka ma paro, Ipinle Oyo ò rerin. Opolopo awon eniyan ni won si ti mu ireti won kuro ninu awon alakoso asiko yii pelu aise ododo ati ifẹ ara ilu.

Igba wo ni ipinle Oyo fe ni gomina ti yoo so ipinle naa dotun. Sebi ajisebi Oyo laari, Oyo kii si sebi baba enikọọkan.

Sugbon sa, awon kan so nipa Onimo-ẹro Seyi Makinde gege bi ọdọ to ni iriri ati imo to jinlẹ, bakan naa lo tun ni itara awon eniyan lokan.

Kini ni ero yin nipa fi fun awon ọdọ ni anfaani lati di ipo giga mu lawujo wa?

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment