Smiley face

[foto] Nicki Minaj pate kaka nla

Ogbontarigi akorinbirin ilu Amerika, Nicki Minaj, ẹni odun metalelọgbọn (33), ti se afihan awon foto re tuntun eleyii ti gbogbo ibara idi re ranju bonbon sita bi oju ọpọlọ. 


Lori ayelujara, awon kan n bu u wi pe ayederu ni gbo "ẹru" iwaju ati teyin nigba ti awon kan si n fi ọwọ mejeeji ko gala rẹ jẹ.
 Bawo le se ri ewa omobirin naa si?


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment