Smiley face

Won ti yinbon pa asofin ipinle Oyo

Gideon Aremu, ti n soju ekun Orelope labe asia egbe oselu Labour ni awon ti fi ibon pa lale ana (01/07/06) nigba to n pada sile re to wa ni agbegbe Alakia niluu Ibadan.

Agbenuso fun ileese olopaa ipinle Oyo, Adekunle Ajisebutu, ti jeri si isele naa. Bakan naa ni won si fi da ara ilu loju lati se awari awon amokun seka naa.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment