Smiley face

Yoruba Dun: Itan igbesi aye Olabisi K (2)


Eyi ni awon esi ati amoran ti awon eniyan fun Olabisi K lori leta re to ko gbeyin. A ko se atunse tabi atunko si awon oro won, bi won se kọ gẹlẹ naa la tun tẹ.
Yoruba Dun: Itan igbesi aye Olabisi K (2)
Abdullahi Bola: Ma jeki ika yen ba e sun,se o mo pe o le ba e sun tan kotun le e nibi ise tabi ko fe maa se lo titi ti yio fi di oyun ti o ofe bi.Olorun le to fun igbesi aye re. Kuro nibe ko o wase lo ibo miran. Omi ti eda o mu koni san koja e. Olorun yio ma lana fun e o. Ameen.


Prince Taofeek Tijjani: Mota arare lopo fu ronu ojo waju e, eka ti oba bao ni asepo ole ba aye re je. Imoran temi nipe ti obani kiofi ise sile OLORUN yio pese ise mi fu o nitori pe OLORUN kiifi eru re sile nigba kakan. Ti obaje pe muslumi tabi cristani bani o gba awe ki ofi be OLORUN OBA lori oro ile aye re OLORUN OBA yio fie si ona toda.OLORUN tio pese ise ye fu o oni agbra lati se imi fu o

Oluwafemi Emmanuel Segun: Be ni, nitori pe ti idi ba baje tan tonidi lo ma da. Awon yoruba lo ma n so wi pe awi fun ni ko to da ni, agba jakadi ni, se owa da ki a fi owo le o n buburu bi eleyi ti ko ba si atunse mon ko. Adara ki a pe ororo ati èdò inú wa ki orí inú ki o ma ba ti òde je .... ......

Babarinde Saheed Olayinka: Omidan Olabisi K imoran temi niyi ki omidan olabisi ma gba ADURA wipe ki olorun ba ohun yii oga ohun lokan pada si rere sugbon ti oga ba ko ti ko fi lorun sile ki omidan olabisi fi ise sile ki o si ma gba ADURA wipe ki olorun pese ise ti o ma fi okan ohun ati oko ohun bale fun awon olorun yio gbo ADURA yin.

Adegbaike Taofeek: Arabinrin Olabisi ma je ko ya o lenu,bi ile aye se baje to lori ye,ni akoko ako mo iru imura ti iwo naa ma mu losi ibi ise re,elekeji sebi gbigbe ni won gbe wa sibe,ni igbagbo won yio gbe lo,so imura re ati wipe omo obirin ko gbodo ma rin erin wedewede ju,ma lo adura yi.Asibunallahi walem wakilu ki o ma daruko Oga naa si,wipe o yo e lenu ki olorun yi ni okan pada tabi ki won gbe kuro ni ibe.ni ase olorun adura re yio gba


Prince Asabi Oluyinka Johnson: Mu oko re afesona lo o ki nigba odun tabi ojo ibi re . Je ki oko re ra nkan to joju fun awon omo re to ba bimo .Se afihan ponmbele fun un pe oko re ni. Mu iyawo re ni ore. Lo ba segun alagbere oga

John Oye: Omidan olabisi k, ko si isoro ti o wa ninu aye eniyan ti ko ni ona abayo, bawo ni omidan yi se ni igbagbo si, ati wipe bawo ni ajosepo pelu olorun se ri. Ko sun mo olorun ti o le se ohun gbogbo, isoro yi le je idanwo lati odo olorun wa ni. Ti Omidan yi ba duro pelu igbagbo ninu olorun yio bori isoro naa.

Obadimeji Ayinde Don'noru Abdulhafeez: Aisinbe laibawondasi, afiki olohun gbawa lowon awon asebi eda,afe aje mofe ayo,tiwon fegbaje lowo eni,adua logbao omoya,olohun fesinlekun aye tojuyanlo fueni,sungbon ofedan'e wo.tori AL-QURAN sope... (leyin inira idekun lokan). kunfu awe pelu adua kiowo arati olohun fefieda,ara ireni yiosifieda logo olohun.ameen.


Wunmi Wale: Ma gba laye lati se iru nkan be be ti ko ba si gbno duro de ojo ti yoo fun o niwe idaniduro kuro nibise mi ki n se kuro laye aleniboro oun loni kenta eni olorun leto fun igbesi aye re osetan lati mu e lo sibi to ga niyen

Ishola Mashood: OMIDAN OLABISI eyan ti ota ara e lopo koni rira gbogbo oro ti owa nile yi iti ogede ni kotoun ti aoyo ada si iwo so ohun ti ofe fun olorun ki ofi ojo ti won bie be olorun walai oga e ma dun nu ni sa ki ode ma fi ise sile ni imoran temi emi ni ki owabi lori oro ise fifi sile

Ogunyinka Ben Felix: Ale fı eleyı we adanwo tı o doju ko josefu nınu bıbelı.mofe kı ese gege bı josefu sese nınu bıbelı.kı ıbere yıı kı osı wa nı okan yın wıpe EMI YIO HA SI SE EYI KI EMI O SISE SI OLORUN MI.(GENESIS 39 VERSE 9).just 3days fastıng&prayer thy lord dat created you,your boss &dat job wıll lead u through.

Otunba Adepoju Amos: Omidan olabisi,imoran temi fun o nipe,magba ki oga ye baye e je.Gbadura si olorun pe ki ola ona abayo,toripe irin ajo eda laye owo olorun lowa.mo daju pe ibiti wade laye wade be dandan ni.

Jacob Adesola Odesina: Arabirin maje ko bae sun o nitori ara re ni tempili oluwa ati boba dao duro ona miran atun si. Tori lati ibere oluwa lo tin bao seto aye re. Ma gbadura tabi ko kuro nibe

Yooba Atata: Ko si ebe ti o le be oga to je agba iya ati aja. Mo be o, ma ta ogo omobinrin re l'opo nitori iberu. Osika ke eni won o le ka ile. Fi okan si odo Olorun.

Aremu Adeniyi Moshood: Omidan seni kio gbokan le olorun tori ohun ti aiye baso eda,niwon afi buhe bodola.Gbe okan re le olohun tori agbe okan le oluwa koni jogun ofo


Adedoyin Fatimah Ojugbele: ki olorun gbawa lowo awon alagbara ti n fi aiye ni eni lara. Amoran temi ni pe gbogbo nkan ti o daa ati tio kudie ounfe adura, oni igbagbo pe ti o ba le gba awe ati adura gbogbo e ani iyanju

Adebayo Luqman Adekunle: Olorun ni kan, ni ole okowayo lowo awon oloriburuku oga bi eyi, eni ti oba gbin ebu ika omore aje ni be, aya re aje nibe, ohun na komoribo, imoron temi fun omidan olabisi ni wipe: ki omafun oga na lanfani lati le basun, ti oba wu ki ole kuro nibi ise, aleni bare ni awon omo eda, ole je wipe olorun fe ki okuro nibi ise nani iru isele be fin sele, olorun yoo pese ise alalubarika miran fun, pelu ogo olorun ki odun yii to pari wa rerin ayo (AMIN)

Ojuade Adeyinka Moses Prince: Omidan OLÁBÍSÍ, a kò lè yí o ní okàn padà, ìmànràn lásán ni tiwa ohun tí ó bá ti okàn re wá ni kí o se. Sùgbón ohun tí ó nbe léyìn èfà, ó ju èje lo. Má ba ojó iwájú ara-àre jé, tí ògá re bá ti ìlèkùn àánú tirè Olórun yo sí tirè sílè gbagada fún o lólá elédùwà.

Onigbinde Ebenezer: Omidan OLABISI; Ti o ba ko iwaju si e taa, ti o ba ko eyin si e taa, sugbon ti o ba ku iwo ni kan, ki o tun ero ara pa. Gba adura ki oko re ni owo lo lati da e ni oko-owoo, nitoripe pupo ninu awon asiwaju wa ni won ti so IBAJE dewu. Ti mo bale ri numba ibanisoro re ni 'inbox' mi ki so itan kekere kan fun e. Sugbon kun fun opolopo adura ati awe.

Adeleye Taoheed Adegoke Jp: Ni won igba ti oga yii ti sope dandan ni ki ohun o bo ni asepo,imoran temi pe ki ofi ise sile koto dipe yio da o duro fun ara re.ati wipe komo base njaba fun o,toripe isubu re ni yio mo wa ni gbogbo igba.


Lawal Tunde Obelawo: Ara isoro towa lorilede wa timonso niyi bi omo obinrin bawa ni ile eko afiki awon oluko rederede riipe awon baa lasepo bibeko kole yege bee lose rii nibise ti kosi ye koribe.imoran temi ni wipe biilekun kan baati imi a sisii kokaenitie odaju pe obaoke a te tie.besini kaagba adura karakara koladura n figba bii kiibase inu mimo igba olorungbo ati inigbagbo pe adurare ti gba ti eyan bati mupe adura na istijaba ni

Abdulqadri Oba Saeed: Hmm baye se rinu,imoran temi nipe mafi ise le oun meji pere lo ni lati se akọọk MAWA SEMI KALE TI OWO BEJU TI BITOWA BAYI L...keji..ya mubádila llrun,gbiyanju KOJI NI DEDE AGO META ORUN tobaje musulum SALUWALA KOWA YAN NFLA MEJI LEYIN SALAM forikan kose asalat mewa kowa so dun kan flrun leyin re se asalat mewa pada kowa pari re pe SUBUANA ROBIKA..sebe fun'jo meta.leyi joketa wabere lowo e pe GA KINNI AFANI TFEJ NIBI TWIYI.kosi esin tiyo fun tayo pe mokan fewo boya m gidi ni ni,besini kese bose wi adua logba le lori i re oo

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment