Smiley face

Aisha Buhari wolu Amerika: Awon ololufee re loju ti Fayose

Iyawo aare Muhammadu Buhari, Aisha Buhari ti bale siluu Amerika bayii.


Eleyii lo waye leyin esun ti Gomina Ayo Fayose fi kan Mama Amina wi pe, won on wa niluu Amerika lori esun ole, gbajue ati makaruru kan to se.
Koda, Fayose tun leri wi pe, ti won ba bi Aisha daa ko yoju siluu Amerika.

Oro Fayose yii lo tun fe jobi eni wi pe otito ni nigba ti iyawo aare fagile irin-ajo re siluu Amerika eleyii ti won ti kede saaju ni akoko naa.

Sugbon lale ana ni mama Zerah, eni ti a bi lodun 1971, to si gba lati di aya Buhari lodun 1989, wo inu Amerika pelu awon isomogbe re. 

Ijo ni won fi n ki kaabo, awon olopaa alawo funfun ti won foju kan Aisha tun beri fun-un.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment