Smiley face

Okiki Omidan ti n se bata ti wo ori ayelujara

Nigba ti awon kan n sunkun wi pe ko si ise lati se, Omidan Michelle Ekure, to kawe gboye ni Ifafiti tilu Benin ti yan ise bata sise laayo.
Ise yii lo ko leyin to pari iwe re ti ko si sise fun un lati se.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment