Smiley face

Asiri: Nje eyin fe ki irun yin gun de ibadi?

Ti e ba fe ki irun yin gun de ibadi, ko tun ma wobo leyin bi oko reluwe, asiri ni yii.

Awon eroja ti e ma wa ni yii: Omi ewe eti erin (aloe vera), Igbo mimu tutu (india hemp)

Ipase: A ma lo omi aloe vera po mo ewe igbo mimu tutu. Eroja meji yii ti a lo papo la ma da sinu iparun (cream) ti a fi n pa irun wa. E wa ma fi pa irun lojoojumo.

O ma je ki irun yin ki lowo, bakan naa ni yoo gun jangbonna bi okun doro.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment