Smiley face

Ewe ati Egbo Yoruba: Eda oju ara obirin

Eroja: Oti Chelsea, red & yellow capsule ati ewe taba

Ipase: E ra red & yellow capsule eyo mewaa (10pieces), e tu awon capsule naa sinu oti Chelsea (igo kekere). Leyin eyi ni e ma lo ewe taba gbigbe papo mo ra won daada.

Bakan naa, e bu sibi ijeun ewe taba teelo meji sinu oti Chelsea kan naa ti e da red & yellow capsule si ninu.

Ti e ba ti se eleyii tan, e fi sile fun ojo meji.

Lilo: Eni naa yoo ma mu soti oti meta leemeta lojumo.

Afikun: ki eni naa fi alum ati ose dudu fo oju ara re.


Olayemi Oniroyin kii se onisegun, iwadii lasan ni mo se lọwọ awon onimo isegun ibile Yoruba.

Edumare to jẹ oluwosan, yo mu gbogbo wa lara da.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment