Smiley face

Ayo Adesanya: E wa woju omo olojo-ibi bo se n dan bi ide

Ayo Adesanya, ogbontarigi osere onitiata ile Naijiria, le lodun ni ijeta, [11-08-16]. Sugbon bayii, omobirin naa ti n se afihan gbogbo faaji to waye ati bo se je igadun ojo ibi re pelu awon foto alaranbara re to fi sita. 

Odun 1969 ni won  bi Ayo Adesanya, ileewe Yunifasiti to wa niluu Ibadan lo si ti kawe gboye ninu imo igbohunsafefe. 

Igba odun, odun kan ni 







Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment