Smiley face

[Audio] Ohun ti Wale Dada se ni yii lojo to reni to fe ga soke

Adewale Dada Thegood
Ile aye yii ile asan ni, E je ki agbe ile aye se rere. Ohun ti a gbese ni koro ma foju han sita lojo kan. Asepamo lo wa, asegbe kan ko si laye. Ohun ti onikaluku ba si gbin lo ma ka. Eniyan ko ni gbin agbado ko wa lo ka mangoro, ko posibu.

Emi o ro wi pe Adewale Dada le se iru nnkan to se yii. 

Kilode to fi wu iru iwa bee? Ki lo wa ninu ero re to fi se ohun to se fun okunrin to pade niluu Oshogbo? Asiko ni yii fun mi lati se afihan iwa Wale Dada fun awon eniyan lati mo iru eda eniyan to je. 
Adewale Dada leyin Gbenga Adeboye, ati Sola Sobowale
Ise iroyin wa lara awon ise to nira ju lagbaye,  sugbon ki ni mo ni lati se  ju ki n so nipa ohun ti oju mi ri lo ati ohun ti mo gbo.  

E gbo alaye lekunrere nibi: DOWNLOAD
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment