Smiley face

Fiimu tuntun Iyabo Ojo ti gori igba: BLACK VAL

Awon Yoruba bo, won ni aileja nita baba mi ko de hin-in. Bi o tile je wi pe pupo awon ololufee Iyabo Ojo mo osere naa mo awon ise fiimu Yoruba, nibayii akoni oserebirin naa ti gbe ise fiimu onigeesi kan jade to pe akole re ni BLACK VAL.

Oni [29-08-16] ni sinima naa yoo gori igba, e gbiyanju ke e mu ti yin.

O si daju wi pe, e ma gbadun re bi eebo ti n gbadun tii.

Ire o!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment