Smiley face

[Foto] Gbajumo ni Mide Funmi Martins lojokojo

Mide Funmi Martins, okan ninu awon osere sinima Nollywood ile Nigeria ni gbajumo wa lose yii.
 Funmi je aya Afeez Owo ti oun naa je osere kan pataki ninu ise tiata Naija.
 A ko le so nipa Mide lai menu ba iya re, Funmi Martins, to fi ise tiata le e lowo. 
 Bi Funmi Martin ko tile si mo, sugbon Mide ko je ki oruko naa di ohun igbagbe lawujo amuludun Naijiria.
Inu ayo ni orekelewa oserebirin naa n gbe pelu oko, Afeez ti won tun mo si Seriki olopolo, lai si wahala. 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment