Smiley face

Foto tuntun omokunrin to di orekelewa obirin

Miss Sahhara tun ti se afihan foto re tuntun. Boya eyin ko tile mo eni ti Miss Sahhara je. Omokunrin ni awon obi re bi saye, sugbon nigba to ya lo pa kadara re da, to si yira pada di orekelewa obirin. Alaye nipa re tun wa NIBI

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment