Smiley face

Tewe-Tegbo Yoruba: Ogun Aran


Aran ma n je ki ounje tete da lara eniyan, eyi si wa lara iwulo re si ara eniyan. Sugbon ti aran ba po lara, o tun le fa akoba. Idi ni yii to fi ye ka dena opolopo aran ni ago ara wa.

Ewe Dingotaro
 Eroja: Ewe dongoyaro (Neem)osan  ati osan wewe (Lime Juice)

Ipese: A ma gbo ewe dongoyaro mo ara won, leyin eyi la ma fun osan wewe bi mewaa sinu re.

Osan wewe
Lilo: Sibi ijeun kan ni aaro ati ni asale ti a ba ti fe sun. To ba je omode ti ojo ori re ko ti ju karun-un lo, sibi omode kan laaro ati lale ni fun un
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment