Smiley face

Iroyin Onifoto: Awon foto mokanlelogun

Awon Yoruba bo, won ni ori taa fi sewe kii kuro lorun eni taa ba dagba. Daddy Showkey ati Oga Nla Fuji (Boss)



Kosi ohun to dun bi ife, ife lakoja ofin. Awon toko-taya musulumi ti n won mura lati se igbeyawo.



Igbe aye C. Ronaldo. Sebi ise ori ran ni laaje. Awon Yooba bọ, won ni ba ti waye láàràí lààríí.


Awon kan ti salaye Mercy Aigbe gege bi eye okin, eye alara oge. ojumo kan ,  aso oge kan ni.

Boda Jelili naa ma n korin to ba pade omoge to joju ni gbese. Koda, Eminado ni bobo naa n ko lenu.


Awon orekelewa omoge ti won dije fun ipo omidan se abewo si Ooni Ogunwusi laafin re. E ma gbegbe wi pe oba lagbara lati gbe ese le won to ba fe. Sebi Yoruba lonii oba bale ohun gbogbo.


Foto ti Yinka Ayefele ya pelu Alaaji Muyideen Bello ni yii ti awon kan fi n gbe aheso oro kiri wi pe, omo Ayefele ti di Musulumi.  Emi ife lasan ni Yinka fi han nigba to pe alufa naa lati wa se waasi awe nile ise orin re.

Iya Aladuke, Osupa ati Mide Funmi Martins


Awon osere leyin itage


Ronke Oshodi Oke: Taa ba sise, ka tun lo se faaju lagbo faaji


9ice ati ebi re. Odun 1980 ni won bi Alexander Abolore Adegbola Adigun Alapomeji Ajifolajifaola ti gbogbo eniyan mo si 9ice. Omo ilu Ogbomoso ni, sugbon Bariga to wa niluu Eko lo dagba si. 

 
Afeez Owo, Seriki olopolo pelu aya re, Mide
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment