Smiley face

"Supamaanu lọkọ mi ooo" Irawo oserebirin onitiata lo so bẹẹ

Kosi ohun to dun bi ki orekelewa obirin ri okunrin gidi fẹ. Ifokanbale nla si ni fun okunrin to ba pade obirin alalubarika to yaayi.
Eyi ni a le fi se apejuwe irawo osere onitiata yii, Arike Akinyanju Balogun. Oko re ko ye e salaye oserebirin ti won tun mo si Eyinju Eledumare gege bi ohun adun kan ti mu igba aye re larinrin pelu afihan awon foto osere naa. E si ti Arike fun oko re pada ni yii leyin aponle to se fun un.

"AYOMI, OKOMI, My very own Daddy IREAYOMI Abdul-Wahab,we love you our superman, and hero"
Ẹ ti ẹ gbọ na, kilo kan mi gan-an lori ọrọ ọlọrọ? Lai se toju bọle ẹran Nuuru?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment