Smiley face

Kini obirin le se ti nnkan osu re ko ba wa daada?

Ti nnkan osu obirin ko ba wa daada gege bo ti ye ko ma wa, ona abayo ni yii.

Ohun ti e ma wa ni ewe eti erin ti awon onigeesi n pe ni Aloe vera. E wa Aloe vera to po die ki e wa gun mo ara won ki won kuna daada.

Leyin eyi, e bu omi die mo aloe vera te e ti gun kuna daada yii.

Lilo:

E gbiyanju ke ma mu glass cup kan laaro ati ni asale fun osu kan.

Olayemi Oniroyin kii se onisegun,
iwadii lasan ni mo se lọwọ awon
Onimo.

Edumare to jẹ oluwosan, yo mu
gbogbo wa lara da.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment