Smiley face

Ewe ati egbo Yoruba: Obirin ti inu run ni akoko nnkan osu re

Ona abayo ni yii fun obirin ti n se nnkan osu ti inu ma n run. Ti o ba je wi pe inu rirun onidodo ni, ohun ti e ma se ni wi pe, e ma wa ewe ewuro, e ma gbo papo pelu omo die.

Leyin ti e ba se eleyii tan, a ma fi kaun bulala die si i. E wa maa mu ni aaro ati lale

Sugbon to ba je inu rirun yoku ni, ewe tea le ma wa. E ma se ewe na , e wa ma mu koopu meta lojumo.


Olayemi Oniroyin kii se onisegun,
iwadii lasan ni mo se lọwọ awon
Onimo.

Edumare to jẹ oluwosan, yo mu
gbogbo wa lara da.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment