Smiley face

Ewe ati egbo Yoruba: Ato okunrin ti ko pe oju osunwon

Eroja: A ma wa ewe gurofa ati omi to loworo die.

Ipase: A ma gbo ewe gurofa yii sinu omi to loworo ti a gbe kale.

Lilo: E ma mu koopu kan laaro lojoojumo fun ose kan.

Akiyesi: E ri wi pe e n gbe omi yii kana leekan lojumo


Olayemi Oniroyin kii se onisegun,
iwadii lasan ni mo se lọwọ awon
Onimo.

Edumare to jẹ oluwosan, yo mu
gbogbo wa lara da.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment