Smiley face

Lara ise iyanu ti ogidi oyin se ni yii

Nnkan ibanuje nla ti oyun ba n wale lara obirin ni gbogbo igba. Awon ti iru nnkan bayii ba n se tabi obirin ti n ri nnkan osu re ninu oyun.

Iwosan to daju wa ninu ogidi oyin.

E je ki iru alaboyun bee ma mu sibi oyin meji ni aro ati lale titi igba ti yoo fi bimo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment