Smiley face

Onisowo so aja re ni Buhari lo ba dero ago olopaa.

Kehinde Oladeji 


Ogbeni Omo ogbon odun kan ti oruko re n je Joe Fortemose Chinakwe ni awon olopaa ti fi sikun ofin mu tori o so aja re ni Buhari, oruko aare ile wa.

Isele yii waye ni ojule kewaa, adugbo omikunle ni Sango-Ota, Ogun State, nigba ti arabinrin kan ti o je eya Hausa fi esun kan Chinakwe pe o so aja re ni oruko Alhaji Buhari. Igba ti onitohun ko ti ko yi oruko aja re pada ni o ba fi oro naa to awon agbofinro leti ti won si ti ju ogbeni naa sinu agodo won bayii.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment