Smiley face

Yoruba Dun: Itan igbe aye Olabisi K (33)



#ayeOlabisiK33

Ẹ le ka itan igbesi aye Olabisi K to ti jade tẹlẹ NIBI ki ẹ to tesiwaju lati ka eleyii ki itan naa le yeyin daada
 
Haolat Precious Bukky: Hmmm Olohun akuku ma fi iso e sowa lowa eni ibi. Ama reti eyi toku, osi dawa loju pe, eko ni fojuwa sona mon.

Udeh Gloria: O ga o!

Aboo Hamzah Bin Saalih: Eyi maa ga o°°°
Eledua o kuku ni yo owo iso re kuro laye wa. Olohun a si maa sowa lowo eni to n soni ta o so. A o maa foju sona, olohun a si maa wa pelu yin.

Temitope Adediran: Eyi ka moomoo, haa!!! o bu haaya... E gbo na, ni bo laye yii wa nlo gan- an?

Adebamiji Oluwafunmibi Lydia: Ibi aye nlo ko seni to ye. Keledua sa ma se amona wa.
Adeleye Taoheed Adegoke Jp: Afi ki olorun kosa nu wa ni ori lede yii.

Adeleye Taoheed Adegoke Jp: Afi ki olorun kosa nu wa ni ori lede yii.

Folorunso Oluwatoyin Ogunpaimo: Olorun a ma kowa yoo.amin

Olaitan Opeyemi: Bi olohun ba n sanu wa,oye kawa naa maa sanu ara wa ni,tori oro wa dabi folohun to lo n fi okun ogede gungi,towa ni ki olohun maa sho ohun,se nigbati olohun so,se o sho ra e,bo seri ni yen.

Omolayo Toyin: Olorun o ni ka eni abo re lori gbogbo wa lori lede yiooooo

Obey Adesoji: ABO OLORUN KO NI KA KURO LORI GBOGBO WA AMIN JESU.

Kolawole Adigun: Hmmm n kan be ee aguntan tii omo e sonu

Oladepo Damilola Samuel: IWE AKAGBADUN Lati øwø j.f Ødunjø pelu iranlowo Tunji Øpadøtun k'ØLØRUN dele feniyan're

Folake Aina Adeleke: Afi ki Olorun ko wa yo lowo awon eni ibi ti ako so t'on sowa o.

Adebisi James Adebayo Ki oluwa ki o gba wa ooo

Adebisi James Adebayo: Ki oluwa ki o gba wa ooo
Adesanya Folashade Asake: Olorun sanu wa ki a ma teni tika. ki oluwa mu ki

Iyanda Adeola Omodele: Abo olorun ko kuku ni fiwasile, Eleda wa koni gbabode loruko jesu.

Prince Taofeek Tijjani: Olorun yio se anu fuwa, akuku ni damu lasan

Olaitan Opeyemi: Amin e poooo,mo sami motun gbe ito adura mi,ORO WOLE,ASE GUN.
Aríyíbí Qósìm Adésolá: E kú làákàyè. Aó máa retí yín.

Sunday Okosun: hnn

Olaitan Opeyemi: Awon agba bo won ni oro tose akalamagbo to fi dekun erin rin,toba se gunnugun a wonkoko mori eni,eledua oba mi oke ko kuku ni gbagbe gbogbo wa sinu aye (e ba n sami tori amin e po).

Ibrahim Abisola Sebastian: lrun a kuku maa s gbogbo wa,abi irú odó wo laa da orunla si bayii,pelu gbogbo alaye oluktan yin,lrun lanb o ki o maa fi wa fun ta mu

Temitope Adediran: Amin o... A a ni si'rin l'ase Eledumare.

Adebamiji Oluwafunmibi Lydia: Amin ase
March 19, 2012 at 10:50am · Like
Olaitan Opeyemi
Olaitan Opeyemi: Oti ri bee,oti se bee,tori kose kose bai ni tilako se.


Ẹ tẹsiwaju ninu itan igbesi aye Olabisi K NIBI

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment