Smiley face

Awon omo Aina ti dagba: Odun ibeji wole de

Ojo ti won bi Taiwo saye ni won bi Kehinde, omo meji to waye leekan soso ni Yoruba n pe n'Ibeji.

Sebi Taiwo lo saaju ki Kehinde o to tele, sugbon ti Yoruba ba ma wi, won a wi pe Kehinde lagba?

Kilode to fi ri bee na?

Sugbon sa, ayo lojo oni [15-09-2016] je fun Taiwo ati Kehinde omo Aina. Oni lojo-ibi omo meji to mu idunnu wole Aina, awon omo meji to sole alakisa donigba aso.

E ku ayo ojo-ibi oni. Igba odun, odun kan ni. Amen
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment