Smiley face

Saheed Osupa ti gba Germany wo ilu Spain

Oba orin Saheed Osupa si n tesiwaju ninu igborinyide re kiri gbogbo ilu Europe.

Gege bi atejade to te Olayemi Oniroyin, lowo, Ilu Jamani lo ti koko bale, nibayi Akorede ti wo ilu Spain lati fi orin ati ilu da awon ololufee re lara ya.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment