Smiley face

Baba Bola Adenuga ti lọ sinmi lẹyin ọdun mejilelọgọrun (102) to lo laye

*K1 de ultimate ni yoo korin nibi ayẹyẹ eto isinku naa  

Adura awon obi ni ki ọmọ rere gbẹyin won laye. Sebi ti ina ba ku a feeru boju, ti ọgẹdẹ ba ku a si fọmọ rẹ rọpọ.

Ilumọọka gbajumọ to fi ilu London se ibujokoo, Bola Adenuga, ni baba to bi i lọmọ, PA SHADRACH ADEOLA ADENUGA ti fi silẹ saye lo bayii. Odun mejilelogorun (102) ni baba oninuure lo laye ko to lọ ba Olugbala rẹ loke ọrun.


Ile aye to dun ni baba gbe, iwa mimọ ni PA SHADRACH ADEOLA ADENUGA fi logba rẹ ni duniyan. Baba jẹ eniyan to nifẹ gbogbo eniyan bakan lo si jẹ oninu didun ọlọrẹ.

Eleyii ko jẹ ko jọ wa loju wi pe awon ọmọ rere ti baba fi silẹ setan lati se ẹyẹ ikẹyin to lọla fun baba to tọ awon ọmọ rẹ bo ti tọ ati bo ti yẹ.

Koda, K1 Ọba Fuji ni yoo kọrin fun awon ọtọkulu ti won yoo pejọ sibi ayẹyẹ ikẹyin naa.

PA SHADRACH ADEOLA ADENUGA


Iroyin to jade nipa ayẹyẹ naa lo wa nisalẹ yii



"LAGOS SOCIALITE, BOLA ADENUGA LOSES DAD AT AGE 102
        
 Famous Lagos and London socialite, Bola Adenuga has lost his dad and for the love he has for the dad, a grand standing burial is scheduled to hold at Ijebu-Mushin come 24th and 25th November, 2016.

Bola Adenuga’s long standing buddy and personal brother, Fuji King, K1 the Ultimate has been confirmed to host all Lagos socialites in the talk-of-the-town event.

 
Late Pa Shadrach Adeola Adenuga is survived by many children, grandchildren and great grandchildren mostly based in the Republic of Ireland, London and Lagos. Amongst them is Mrs Olubunmi Adenuga.

Burial preparations is in top gear and major Lagos socialites like Taiwo Afolabi of Sifax, top hotelier, Lanre Mohammed (Lamex), Honourable Kunle Sanyaolu, Lanre Ijaola (Ijakoko) and Tunde Akinyera are all in the planning team for a showdown at Ijebu-Mushin come 24th and 25th of November, 2016."
  

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

1 comments: