Smiley face

D-Romola lori @RadioDiasporang pelu @OlayemiOniroyin

Niluu Ile Ifẹ, ko sẹni ti o sai mo wi pe Ooni Enitan Adeyeye Ogunwusi ni i sade ori won nibẹ. Ooni Ojaja ọba alasọ funfun bi lekeleke, ẹrujẹjẹ olowo-ori Wuraola ni Arole Odua asiko yii. 


D-Romola
D-Romola ko pe meji ni gbogbo ilu London to fi de Dublin, ẹyẹ ti o dorikodo bi adan o si lori igi. 
To ba jẹ ti orin ẹmi to gbamuse tabi orin juju to ta lẹnu bi ata suya, D-Romola ni Oba oke gbe fun. Bo se n korin fun akátá ni i lulu alujo feeyan dudu.

Eni Olorun da ko see fara we!

Lojo kokandinlọgbọn osu kewaa odun yii, 29-10-2016, D-Romola yoo ma sokalẹ sori eto mi lati ilu London, ni deede ago mesan-an owuro. Gọngọ asọ!

E ma gbagbe, ori itakun agbaye www.radiodiaspora.com.ng ni e ma ti je igbaladun eto naa.

E ku oju lọna!







Ninu awon iroyin mii

[Audio] Gbedemuke pelu @OlayemiOniroyin: http://bit.ly/2dzN4zb 


[Audio] "Mi ò le kọ isẹ ìlù lilu lai ma kọ èdè Yoruba" - Ayantunde Anselm Ramacher omo ilu Germany: http://bit.ly/2e82J7D  #Gbedemuke

 
Clemso: Omo Naijeria juko ỌRỌ lati ilu Finland: http://bit.ly/2drNHNS

 
Pasuma ti da Fela Anikulapo pada wa saye ooo http://dlvr.it/MNtrhZ  http://fb.me/1nRE2ZbSq

 
[Audio] Naija @56 Happy Independence Day: Download
https://t.co/9d0oFWC8RQ
 

Bayii ni e se le se awari ebun yin
https://t.co/WBtdYv1uGa


Gbedemuke: Clemso lati ilu Finland ni alejo mi lose yii: Eto Gbedemuke ose yii yoo tun lagbara pupo

https://t.co/4FJPzUBS0o
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment