Smiley face

E wa wo iro ti awon obirin n pa nibi

https://web.facebook.com/groups/letakanako/permalink/1345636628820976/?comment_id=1351523084898997&notif_t=group_comment_reply&notif_id=1479934978757845
Lati ori Facebook Yoruba Dun ni enikan ti beere boya o seese fun awon obirin lati lo osu meje lai ni ibalopo. 

Gbogbo idahun awon obirin ni awon okunrin ko gba, won ni iro ni gbogbo won pa. 

E gbo, se o posibu fun obirin lai ni ibalopo fun osu meje?

E wo idahun awon eniyan NIBI
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment