Smiley face

[Foto] Awon onisẹ oge tako Mercy Aigbe lori imura rẹ yii

Mercy Aigbe
Gẹgẹ bi alaye awon onisẹ oge sise, won ni iru awọ asọ Mercy daraju fun ẹni ti awọ ara rẹ ba dudu, eleyii yoo tun bọ mu ki ẹwa asọ rẹ yọ jade daada. 

Subon sa, bi o tilẹ je wi pe Mercy Aigbe ko dudu, sibesibe, asọ naa rẹwa lara re gidi gan-an. Gbogbo eroja to si lo lo se wẹku pẹlu asọ naa; lati ibi ilẹkẹ ọrun, tọwọ, ati ago olomi goolu rẹ lo fakiki.
 Ka ma parọ, Mercy rẹwa lobirin...

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment