Smiley face

Kola Olootu: Oni lọjọ ibi Baasọrọ Ile Yoruba

http://www.olayemioniroyin.com/search?q=kola+olootu
Kola Olootu
Ọdẹ to ba jẹ ogboju ọdẹ gidi, won ki i lofunpa ki won to rode ẹran pipa. Meloo leyin ri lorun Kola Akintayo ọdẹ Ilubadan?

Bi Akolawole Olootu ko ba lo ilẹkẹ sọrun ti o si  gbade funfun sori rode ariya, kosi ẹni ti o mọ wi  pe ọmọ Adabanija ni Adimula gbogbo sọrọsọrọ ilẹ yii pata. Baasọrọ Ile Yoruba ko pe meji!

Happy Birthday! Igba odun odun kan ni.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment